NewStats: 3,264,647 , 8,184,327 topics. Date: Wednesday, 11 June 2025 at 08:39 PM 572z3h6z3e3g |
(2) (3) (of 3 pages)
![]() |
Gomina ipinle Ekiti, Ayodele Fayose ti ni ki Baba Obasanjo daa pada bi owo baba'jebu. O ni Jonathan sise gidi gaan nigba ti o wa lori aleefa.... Nje e gbagbo pe looto ni? Iroyin yen po ju bayen lo.... www.sisigbeborun..com
|
![]() |
Hehehe, iwo lo ro be...nje omo Yoruba tooto ni e?
|
![]() |
L'ana ode yi ni MAMA2015 waye ni ilu South Africa, to si je wipe awon omo Naija ko meje(7) ninu gbogbo awon ami eye(Awards) ti won fi da awon olorin lati ile adulawo(African Artistes) l'ola... E woo, ki n ma soro ju, e ka ekunrere awon ishele yen ni'bi - www.sisigbeborun..com |
![]() |
Omo olojo ibi, Ayo Balogun ti gbogbo eniyan mo is Wizkid ti pe omo odun meedogbon loni. O si ti n gbaradi lati fo lo is ilu South Africa fun ipalemo MAMA award ti o ma waye ni ojo abameta ti o nbo yi. Wizkid yio se ayeye ojo ibi re pelu awon olorin jankan jakan ni South Africa paapa julo awon ti won jo ma fi orin da awon eyan l'araya ni MAMA award. O ku oriire o. Oluwa a de e is fun wa. Eyin ololufe Wizzy, e ya ki ku oriire |
![]() |
omitooguns: Itan yen da le ori awon akoni meje ti won won lo si'nu igbo irunmole. L'ara won ni Akara oogun, Imodoye, Olohun Iyo, Kako onikumo ekun, ati bee bee lo. Ibi ti mo feran ju ninu iwe yi ni ibi ti won ti so wipe "Awa ti a je akoni je meje"....hehehe 1 Like |
![]() |
Itan je ohun to se pataki lati igba awon baba baba wa, le yi to je pe won tun fi le awa odo isin yi l'owo. E je ki a wo itan "Akara Oogun" ninu iwe "Ogboju Ode Ninu Igbo Irunmole". Itan yi je okan pataki ninu awon itan isembaye ti o is je wipe sasa ni ogidi omo Yoruba ti ko ti ni gbo ri. O daa, ewo ni eyin ranti ![]() 1 Like |
![]() |
Bawo ni obinrin se ma feran moto ju omo bibi inu e lo?? Kayeefi nla.... Hmmm... Oritsefemi dubule aisan - o ma se o.... E ka ekunrere awon iroyin wonyi ni www.sisigbeborun..com. |
![]() |
Call it an innovation, call it breaking away from the norm, it's a way to bring the youths to the realisation that our language(Yoruba) must not be thrown away all in the name of western influence or computer age.
|
![]() |
Are you tired of reading stories from different blogs/websites in English language? Igba otun ti de o. E lo taara si www.sisigbeborun..com lati ka iroyin nipa oselu, oge sise, oro to nlo, abbl, ni ede Yoruba. O ta l'enu gaan.....
|
![]() |
If you speak and/or write the yoruba language very well, then this is for you. The Yoruba language is a very rich one and it will be nice if we can promote it the best way we can. Visit www.sisigbeborun...com for latest gists and juicy gossips ![]() |
(2) (3) (of 3 pages)
(Go Up)
Sections: How To . 11 Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or s on Nairaland. |