NewStats: 3,262,601 , 8,177,660 topics. Date: Monday, 02 June 2025 at 11:57 PM 673216z3e3g |
Ifa Divination For The Month Of April 2012 (2164 Views)
(1) (Reply)
OBAONIMOLE(m): 9:38am On Apr 04, 2012 |
OSE OTURA Akuree akuree oregbe nikurekure kaka komo awo oku iroke adaa ipese afaya ,omo awo koni ku iroke konida ipese konifaya difa oluogirika omo afebo tiku orun gbonyin gbonyin mare,won npe oluogirika lorun koje ebo lofinsowo siwon ,kini oluogirika fijepe ebo ni oluogirika fijepe ebo agogo idée kiyun nimaro,ajaa tikoni omo ninu kijepe orisa lagidigbo kibawon yun morun,oluogirika pele o.omo afebo tikuu orun gbonyin gbonyin mare. IFA ni osu ti awayi,osu Kerin odun wipe osu ibukun,ilosiwaju ati isegun aiku ni fun gbogbo wa ,wipe ki akun fun adura,ki asi safun ese towun ipani lara ,ki amasi peri omo lakeji wa nibi,IFA ni ki amarubo dada ki asima se adura ,ki asima bo eleda wa dede ki asimani emii idarijin IFA DIVINATION FOR THE MONTH OF APRIL 2012 OSE OTURA IFA says this month we are is a month of greatness,succes,overcome death for all IFA says we should all be prayerful and should not bad bite IFA says we should not say a bad curse on our fellow human beings IFA says will should be very prayerful and worship our ORI (DESTINY) IFA OLODUMARE WILL BE WITH ALL.ASE O 1 Like |
(1) (Reply)
Emir Of Rano Steps Out In Style As He Checks Out His Freshly Created Emirate
(Go Up)
Sections: How To . 7 Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or s on Nairaland. |